Home Page »  K »  Kayode
   

Aimoye Lyrics


Kayode Aimoye

[Intro: Kayode, King Dr. Saheed Osupa]
Aimoye awọn eniyan, to ti lọ nile aye
Aimo—, aimoye awọn eniyan
To ti lọ n—, to ti lọ n—
Aimoye awọn eniyan, to ti lọ nile aye
Aimo—, aimoye awọn eniyan
To ti lọ n—, to ti lọ n—
Aimoye awọn eniyan, to ti lọ nile aye
Aimo—, aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ n—, to ti lọ n—
Aimoye awọn eniyan (Aimoye), to ti lọ nile aye (Aimoye)
Aimo—, aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ n— (K—, K—, Kay')

[Verse 1: Kayode, King Dr. Saheed Osupa]
Yeah, kilowade gan-na?
You know you be feeling the boy's swag
Ice on my neck tan-na (Ice)
Bawo lo ṣe'n wa gan-na
Ko si n' tẹ ma ṣe, on God (Àgé)
Why you come dey para, para, para
Para, para, para, better comport, comport (Abeg, abеg)
Me I no fit gree, me I no fit wait
Ṣe you see mе do like dondos?
Ọmọ ọgbọn ni mi, I no even like to dey do Oscroh
Aimoye awọn—, Aimoye
Nigga toti wa to ti fọ, to ti lọ
T'ọmọ l'ọmọ oti Bob (Bob), ma lọ ma gbogbo si, gbogbo si

[Chorus: Kayode, King Dr. Saheed Osupa]
Aimoye awọn eniyan (Yeah, aimoye)
To ti lọ nile aye (Yeah, aimoye)
Aimo—, aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ n—, to ti lọ n— (Yeah, yeah)
Aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ nile aye (Yeah, aimoye)
Aimo—, aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ n—, to ti lọ n—
Aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ nile aye (Yeah, aimoye)
Aimo—, aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ n—, to ti lọ n— (Yeah, yeah)
Aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ nile aye (Yeah, aimoye)
Aimo—, aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ n—, to ti lọ n—

[Verse 2: Kayode, King Dr. Saheed Osupa]
Ọlọrun lo mọ o, ọlọrun lo mọ o, ah
Ẹda to n ṣ'ika, t'aye ro b'oṣe're o
Oluwa lo ye o (Oluwa lo ye o), ah (Kay Kay)
Mo k'àwọn ènìyàn tàn, ọmọ ni mo ti binu pé kí ni mo jẹ? (Ki ni mo—)
Ki ni mo fa? Ki ni mumu? (Ah)
Wọn ni bawo ni, bawo ni, ba—, wọn ni ba ni
Ṣa I don bail my p'emi dẹbẹ
Enemies, wey dey bail me wa lẹ (Like, like)
Ọlọrun lo mọ o

[Chorus: Kayode, King Dr. Saheed Osupa]
Aimoye awọn eniyan (Yeah, aimoye)
To ti lọ nile aye (Yeah, aimoye)
Aimo—, aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ n—, to ti lọ n— (Yeah, yeah)
Aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ nile aye (Yeah, aimoye)
Aimo—, aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ n—, to ti lọ n—
Aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ nile aye (Yeah, aimoye)
Aimo—, aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ n—, to ti lọ n— (Yeah, yeah)
Aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ nile aye (Yeah, aimoye)
Aimo—, aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ n—, to ti lọ n—
Most Read Kayode Lyrics


post malone to perform at 2026 fifa world cup closing ceremony
Post Malone To Perform At 2026 Fifa World Cup Closing Ceremony
Faith Thompson - 14 Jul 2026
music, tours, and motherhood: how rihanna stays connected on the road
Music, Tours, And Motherhood: How Rihanna Stays Connected On The Road
Evren E. - 29 Jun 2026
tom holland marries zendaya in a private wedding ceremony
Tom Holland Marries Zendaya In A Private Wedding Ceremony
Sasha Mednikova - 16 Jun 2026
the new hitmakers: how social media is rewriting the rules of music discovery
The New Hitmakers: How Social Media Is Rewriting The Rules Of Music Discovery
Chris Page - 05 Jun 2026
katy perry brings massive free concert to mexico fenapo festival
Katy Perry Brings Massive Free Concert To Mexico Fenapo Festival
Faith Thompson - 27 May 2026
Browse: